Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì ń wí fún àwọn òkè àti àwọn àpáta náà pé, “Ẹ wó lù wá, kí ẹ sì fi wá pamọ́ kúrò lójú ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́, àti kúrò nínú ìbínú Ọ̀dọ́-Àgùntàn náà:

Ka pipe ipin Ìfihàn 6

Wo Ìfihàn 6:16 ni o tọ