Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ẹ̀dá tí o sì ń bẹ ni ọ̀run, àti lórí ilẹ̀ ayé, àti nísàlẹ̀ ilẹ̀ àti irú àwọn tí ń bẹ nínú òkun, àti gbogbo àwọn tí ń bẹ nínú wọn, ni mo gbọ́ tí ń wí pé,“Kí a fi ìbùkún àti ọlá, àti ògo, àti agbára,fún Ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́ àti fún Ọ̀dọ́-Àgùntànnáà láé àti láéláé.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 5

Wo Ìfihàn 5:13 ni o tọ