Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 5:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì wò, mo sì gbọ́ ohùn àwọn ańgẹ́lì púpọ̀ yí ìtẹ́ náà ká, àti yí àwọn ẹ̀dá alààyè náà àti àwọn àgbà náà ká: Iye wọn sì jẹ́ ẹgbàárun ọ̀nà ẹgbàarún àti ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọ̀nà ẹgbẹẹgbẹ̀rún.

Ka pipe ipin Ìfihàn 5

Wo Ìfihàn 5:11 ni o tọ