Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà, tí olúkúlùkù wọn ni ìyẹ́ mẹ́fà, kún fún ojú yíká ara àti nínú; wọn kò sì sinmi lọ́sàn-ań àti lóru, láti wí pé:“Mímọ́, Mímọ́, Mímọ́,Olúwa Ọlọ́run Olódùmare,tí ó ti wà, tí ó sì ń bẹ, tí ó sì ń bọ̀ wá!”

Ka pipe ipin Ìfihàn 4

Wo Ìfihàn 4:8 ni o tọ