Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti láti ibi ìtẹ́ náà ni òkun bi digi wà tí o dàbí Kírísítálì: Àti yí ìtẹ́ náà ká ní ẹ̀gbẹ́ kọ̀ọ̀kan ni ẹ̀dá alààyè mẹ́rin tí ó kún fún ojú níwájú àti lẹ̀yìn wà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 4

Wo Ìfihàn 4:6 ni o tọ