Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 19:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì gbọ́ bí ẹni pé ohùn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn, àti bí ìró omi púpọ̀, àti bí ìró àrá ńláńlá, ń wí pé:“Halelúyà!Nítorí Olúwa Ọlọ́run wa, Olódùmarè ń jọba.

Ka pipe ipin Ìfihàn 19

Wo Ìfihàn 19:6 ni o tọ