Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 19:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wólẹ̀ ní ẹsẹ̀ rẹ̀ láti foríbalẹ̀ fún un. Ó sì wí fún mi pé, “Wò ó, má ṣe bẹ́ẹ̀: ìránṣẹ́ ẹlẹ́gbẹ́ rẹ̀ ni èmi, àti ti àwọn arákùnrin rẹ̀ tí wọ́n di ẹ̀rí Jésù mú: foríbalẹ̀ fún Ọlọ́run: nítorí pé ẹ̀rí Jésù ni ìsọtẹ́lẹ̀.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 19

Wo Ìfihàn 19:10 ni o tọ