Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 17:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì fi aṣọ elése àlùkò àti aṣọ odòdó wọ obìnrin náà, a sì fi wúrà àti òkúta iyebíye àti pérílì ṣe é lọ́sọ̀ọ́, ó ní ago wúrà kan ní ọwọ́ rẹ̀, tí ó kún fún ìríra àti fún ẹ̀gbin àgbérè rẹ̀;

Ka pipe ipin Ìfihàn 17

Wo Ìfihàn 17:4 ni o tọ