Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 17:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì gbé mi nínú ẹ̀mí lọ sí ihà: mo sì rí obìnrin kan ó jòkòó lórí ẹranko aláwọ̀ òdòdó kan tí ó kún fún orúkọ ọ̀rọ̀ òdì, ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá.

Ka pipe ipin Ìfihàn 17

Wo Ìfihàn 17:3 ni o tọ