Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 16:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì fi oru ńlá jó àwọn ènìyàn lára, wọ́n sì sọ̀rọ̀ òdì sí orúkọ Ọlọ́run, ẹni tí ó ní agbára lórí ìyọnu wọ̀nyí: wọn kò sì ronúpìwàdà láti fi ògo fún un.

Ka pipe ipin Ìfihàn 16

Wo Ìfihàn 16:9 ni o tọ