Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti àwọn tí o ń gbé orí ilẹ̀ ayé yóò sì yọ̀ lé wọn lórí, wọn yóò sì ṣe àríyá, wọn ó sì ta ara wọn lọ́rẹ; nítorí tí àwọn wòlíì méjèèjì yìí dá àwọn tí o ń bẹ lórí ilẹ̀ ayé lóró,

Ka pipe ipin Ìfihàn 11

Wo Ìfihàn 11:10 ni o tọ