Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 10:9-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Mo sì tọ ańgẹ́lì náà lọ, mo sì wí fún pé, “Fún mi ní ìwé kékeré náà.? Ó sì wí fún mi pé, ‘Gbà kí o sì jẹ ẹ́ tan: yóò dàbí oyin.’ ”

10. Mo sì gba ìwé kékeré náà ni ọwọ́ ańgẹ́lì náà mo sì jẹ ẹ́ tan; ó sì dùn lẹ́nù mi bí oyin; bí mo sì tí jẹ ẹ́ tan, inú mi korò.

11. A sì wí fún mi pé, “Ìwọ ó sì tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ènìyàn, àti orílẹ̀ àti èdè, àti àwọn ọba.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 10