Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi ni Álfà àti Òmégà,” ni Olúwa Ọlọ́run wí, “ẹni tí ó ń bẹ, tí ó ti wà, tí ó sì ń bọ̀ wá, Olódùmarè.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 1

Wo Ìfihàn 1:8 ni o tọ