Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 1:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun ìjìnlẹ̀ tí ìràwọ̀ méje náà tí ìwọ rí ní ọwọ́ ọ̀tún mi, àti ọ̀pá wúrà fìtílà méje náà. Ìràwọ̀ méje ni àwọn ańgẹ́lì ìjọ méje náà: àti ọ̀pá fìtílà méje náà ní àwọn ìjọ méje.

Ka pipe ipin Ìfihàn 1

Wo Ìfihàn 1:20 ni o tọ