Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Lídà sì ti súnmọ́ Jópà, nígbà tí àwọn ọmọ-ẹyìn gbọ́ pé Pétérù wà níbẹ̀, wọ́n rán ọkùnrin méjì sí i láti bẹ̀ ẹ́ pé, “Má ṣe jáfara láti dé lọ́dọ̀ wa.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:38 ni o tọ