Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwẹ̀fà náà sì sọ fún Fílípì pé, “Mo bẹ̀ ọ́ sọ fún mi, nípa ta ni wòlíì náà ń sọ ọ̀rọ̀ yìí, nípa ara rẹ̀ tàbí nípa ẹlòmìíràn?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:34 ni o tọ