Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fílípì si súré lọ, ó gbọ́ ti ó ń ka ìwé wòlíì Àìṣáyà, Fílípì sì bí i pé, “Ohun tí ìwọ ń kà yìí ha yé ọ bí?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:30 ni o tọ