Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ́ọ̀lù sì wà níbẹ̀, ó sì ní ohùn sí ikú rẹ̀.Ní àkókò náà, inúnibini ńlá kan dìde sí ìjọ tí ó wà ni Jerúsálémù, gbogbo wọn sì túká káàkiri agbègbè Jùdíà àti Samaríà, àyàfi àwọn àpósítélì.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 8:1 ni o tọ