Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì sọ báyìí pé: ‘Irú-ọmọ rẹ̀ yóò ṣe àtìpó ni ilẹ̀ àjèjì; wọn ó sì sọ wọn di ẹrú, wọn ó sì pọ́n wọn lójú ni irínwó ọdún.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:6 ni o tọ