Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:58 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n sì wọ́ ọ sẹ́yìn òde ìlú, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ ọ́ ní òkúta; àwọn ẹlẹ́rìí sì fi aṣọ wọn lélẹ̀ lẹ́sẹ̀ ọmọkùnrin kan tí a ń pè ní Sọ́ọ̀lù.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:58 ni o tọ