Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ̀yin ọlọ́rùn-líle àti aláìkọlà àyà àti etí! Bí àwọn baba yín gẹ́lẹ́ ni ẹ̀yín rí: Nígbà gbogbo ni ẹ̀yin máa ń dènà Ẹ̀mí Mímọ́!

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:51 ni o tọ