Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:47-49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

47. Ṣùgbọ́n Sólómónì ni ó kọ́ ilé fún un,

48. “Ṣùgbọ́n Ọ̀gá-ògo kì í gbé ilé ti a fi ọwọ́ kọ́: gẹ́gẹ́ bí wòlíì ti wí pé:

49. “ ‘Ọ̀run ni ìtẹ́ mi,ayé ni àpòtí ìtìsẹ̀ mi.Irú ilé kínní ẹ̀yin yóò kọ́ fún mi?ni Olúwa wí.Tàbí níbo ni yóò jẹ́ ibi isinmi mi?

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7