Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìdáhùn sí èyí ó wí pé, “Ẹ̀yin arakùnrin àti ẹ̀yin baba, ẹ fetísílẹ̀ sí mi! Ọlọ́run ògo fi ara hàn fún Ábúráhámù baba wa, nígbà tí ó wà ni Mesopotamíà, kí ó to ṣe àtìpó ni Háránì.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:2 ni o tọ