Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn méjìlá sì pe ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn jọ sọ́dọ̀, wọn wí pé, “Kò yẹ kí àwa ó fi ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sílẹ̀, kí a sì máa ṣe ìránṣẹ́ tábílì.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:2 ni o tọ