Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ ní ọjọ́ wọ̀nyí, nígbà tí iye àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ń pọ̀ sí i, ìkùn-sínú wà ní àárin àwọn Gíríkì tí se Júù àti àwọn Hébérù tí se Júù, nítorí tí a gbàgbé nípa ti àwọn opó wọn nínú ìpín-fúnni ojoojúmọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:1 ni o tọ