Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì gbà ìmọ̀ràn rẹ̀. Wọn pe àwọn àpósítélì wọlé, wọ́n lù wọ́n. Wọn sí kìlọ̀ fún wọn pé kí wọn má ṣe sọ̀rọ̀ ni orúkọ Jésù mọ́, wọ́n sì jọ̀wọ́ wọn sílẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:40 ni o tọ