Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ẹnìkan dé, ó wí fún wọn pé, “Wò ó, àwọn ọkùnrin tí ẹ̀yin fi sínú túbú wà ní tẹ́ḿpílì, wọn dúró wọ́n sì ń kọ́ àwọn ènìyàn.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 5:25 ni o tọ