Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí èyí yé gbogbo yín àti gbogbo ènìyàn Ísírẹ́lì pé, ni orúkọ Jésù Kírísítì ti Násárétì, tí ẹ̀yin kàn mọ́ àgbélébùú, tí Ọlọ́run jí dìde kúrò nínú òkú, nípa rẹ̀ ni ọkùnrin yìí fi dúró níwájú yín ni ara dídá-ṣáṣá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:10 ni o tọ