Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ṣíṣe nǹkan wọ̀nyí, wọ́n rí mí nínú iyẹ̀wù tẹ́ḿpílì, bí mo ti ń parí ètò ìwẹ́nú, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe ní àárin àwùjọ ènìyàn, tàbí pẹ̀lú ariwo.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:18 ni o tọ