Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n, èmí jẹ́wọ́ fún ọ pé, èmi ń sin Ọlọ́run àwọn baba wa gẹ́gẹ́ bí èmi ti ń tẹ̀le ọ̀nà tí wọ́n ń pè ni ìyapa-ìsìn. Èmi ń gbá gbogbo nǹkan ti a kọ sínú ìwé òfin gbọ́, àti tí a kọ sínú ìwé àwọn wòlíì,

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:14 ni o tọ