Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ọjọ́ márùn-ún Ananíyà olórí àlúfáà náà sọkalẹ̀ lọ pẹ̀lú àwọn alàgbà àti ẹnìkan, Tátúlù agbẹjọ́rò, ẹni tí ó sọ̀rọ̀ ẹjọ́ Pọ́ọ̀lù fún baálẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:1 ni o tọ