Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí a sì tí jí i sọ fún mi pé, wọn yóò dènà de ọkùnrin náà, mo rán an sí ọ lọ́gán, mo sì pàṣẹ fún àwọn olùfisùn rẹ̀ pẹ̀lú, láti sọ ohun tí wọ́n bá rí wí sí i níwájú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:30 ni o tọ