Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì pe méjì nínú àwọn balógun ọ̀run sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì wí pé, “Ẹ múra igba ọmọ-ogun sílẹ̀, láti lọ ṣí Kesaríà, àti àádọ́rin ẹlẹ́ṣin, àti igba ọlọ́kọ̀, ní wákàtí kẹ́ta òru.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:23 ni o tọ