Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú un, ó sì sìn ín lọ sọ́dọ̀ olórí-ogun.Balógun ọ̀rún náà wí pé, “Pọ́ọ̀lù òǹdè pè mi sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sí bẹ̀ mí pé ki èmi mú ọmọkùnrin yìí tọ̀ ọ́ wá, ẹni tí ó ní nǹkan láti sọ fún ọ.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:18 ni o tọ