Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójijì ìró sì ti ọ̀run wá, gẹ́gẹ́ bí ìró ẹ̀fúùfù líle, ó sì kún gbogbo ilé níbi tí wọ́n gbé jókòó.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:2 ni o tọ