Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin kan fi ara mọ́ ọn, wọ́n sì gbàgbọ́: nínú àwọn ẹni tí Díónísíù ara Aréópágù wà, àti obìnrin kan tí a ń pè ni Dámárì, àti àwọn mìíràn pẹ̀lú wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:34 ni o tọ