Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:33-34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

33. Bẹ́ẹ̀ ni Pọ́ọ̀lù sì jáde kúrò láàrin wọn.

34. Ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin kan fi ara mọ́ ọn, wọ́n sì gbàgbọ́: nínú àwọn ẹni tí Díónísíù ara Aréópágù wà, àti obìnrin kan tí a ń pè ni Dámárì, àti àwọn mìíràn pẹ̀lú wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17