Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọn sì ti ń la àwọn Ìlú lọ, wọ́n ń fi àwọn àṣẹ, tí a tí pinnu láti ọ̀dọ̀ àwọn àpósítélì àti àwọn alàgbà tí ó wà ní Jerúsálémù, lé wọn lọ́wọ́ láti máa pa wọ́n mọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:4 ni o tọ