Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì mú wọn wá ṣí ilé rẹ̀, ó sì gbé ounjẹ kalẹ̀ níwájú wọn, ó sì yọ̀ gidigidi pẹ̀lú gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀, nítorí ó gba Ọlọ́run gbọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:34 ni o tọ