Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójijì ilẹ̀ mímì ńlá sì mi, tóbẹ́ẹ̀ tí ìpilẹ̀ ile túbú mì tìtì: lọ́gán, gbogbo ilẹ̀kùn sì sí, ìde gbogbo wọn sì tú ṣílẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:26 ni o tọ