Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí a sí bamitíìsì rẹ̀, àti àwọn ara ilé rẹ̀, ó bẹ̀ wá, wí pé, “Bí ẹ̀yin bá kà mí ni olóòtọ́ sí Olúwa, ẹ wá si ilé mi, kí ẹ sí wọ̀ níbẹ̀!” O sí rọ̀ wá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:15 ni o tọ