Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́jọ́ ìsinmi, àwa sí jáde lọ sí ẹ̀yìn odi ìlú náà, lẹ́bá odò kan, níbi tí a rò pé ibi àdúrà wà; àwa sí jókóò, a sì bá àwọn obìnrin tí o péjọ ṣọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:13 ni o tọ