Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn kan ti ẹ̀yà àwọn Farisí tí wọ́n gbàgbọ́ dìde, wọ́n ń wí pé, “A ní láti kọ wọ́n ní ilà, àti láti pàṣẹ fún wọn pé kí wọn máa pa òfin Mósè mọ́.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:5 ni o tọ