Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n kò fi ara rẹ̀ sílẹ̀ ní àìní ẹ̀rí, ní ti pé ó ṣe rere, ó ń fún yín lójò láti ọ̀run wá, àti àkókò èso, ó ń fi oúnjẹ àti ayọ̀ kún ọkàn yín.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:17 ni o tọ