Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ará, ẹ̀yin ọmọ ìran Ábúráhámù, àti ẹ̀yin ti ó bẹ̀rù Ọlọ́run, àwa ni a rán ọ̀rọ̀ ìgbàlà yìí sí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:26 ni o tọ