Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Jòhánù sì ti ńlá ipa tirẹ̀ já, ó ni, ‘Ta ni ẹ̀yin ṣèbí èmi jẹ́? Èmi kì í ṣe òun. Ṣùgbọ́n ẹ kíyèsí í, ẹnìkan ń bọ̀ lẹ́yìn mi, bàtà ẹsẹ̀ ẹni tí èmi kò tó tú.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:25 ni o tọ