Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn kíka ìwé òfin àti ìwé àwọn wòlíì, àwọn olórí sínágọ́gù ránṣẹ́ sí wọn, pé, “Ará, bí ẹ̀yin bá ni ọ̀rọ̀ ìyànjú kan fún àwọn ènìyàn, ẹ sọ ọ́!”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:15 ni o tọ