Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ni ọjọ́ àfiyèsí kan, Hẹ́rọ́dù sì wà nínú aṣọ ìgúnwà rẹ̀, ni orí ìtẹ́ rẹ̀, ó sì ń bá àwọn àjọ ènìyàn sọ̀rọ̀ ní gbangba.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:21 ni o tọ