Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tó sì rò ó, ó lọ sí ilé Màríà ìyá Johánù, tí àpélè rẹ̀ ń jẹ́ Máàkù; níbi tí àwọn ènìyàn púpọ̀ pejọ sí, tí wọn ń gbàdúrà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:12 ni o tọ