Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Pétérù sì ti ń sọ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí lẹ́nu, Ẹ̀mí Mímọ́ bà lé gbogbo àwọn ti ó gbọ́ ọ̀rọ̀ náà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:44 ni o tọ